Jẹ́nẹ́sísì 41:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn màlúù tí ó rù, tí kò sì lẹ́wà sì gbé àwọn tí ó lẹ́wà tí ó sanra jẹ. Nígbà náà ni Fáráò jí.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:1-13