Jẹ́nẹ́sísì 41:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò sì bi wọ́n pé, “Ǹjẹ́ a le rí ẹnikẹ́ni bi ọkùnrin yìí, nínú ẹni tí ẹ̀mí Ọlọ́run ń gbé?”

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:28-42