Jẹ́nẹ́sísì 41:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí wọn kó gbogbo oúnjẹ ilẹ̀ náà ni àwọn ọdún méje ọ̀pọ̀ yìí, kí wọn sì kó àwọn ọkà tí wọn jẹ sẹ́kù pamọ́ lábẹ́ aṣẹ Fáráò. Kí a kó wọn pamọ́ ni àwọn ìlú fún jíjẹ.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:28-37