Jẹ́nẹ́sísì 41:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A kò ní rántí àsìkò ọ̀pọ̀ oúnjẹ yanturu náà mọ́ nítorí pé ìyàn tí yóò tẹ̀lé e yóò pọ̀ púpọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:23-32