Jẹ́nẹ́sísì 41:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

sì kíyèsí i, màlúù méje tí ó sanra tí o sì lẹ́wà jáde wá, wọ́n sì ń jẹ koríko ní tòsí ibẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:13-21