Jẹ́nẹ́sísì 41:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣẹ́fù dáhùn pé, “kì í ṣe agbára mi, ṣùgbọ́n, Ọlọ́run ni yóò fún Fáráò ní ìtúmọ̀ àlá náà.”

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:9-22