Jẹ́nẹ́sísì 40:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí agbọ́tí sì ṣọ́ àlá rẹ̀ fún Jósẹ́fù, wí pé, “Ní ojú àlá mi, mo rí àjàrà kan (tí wọn ń fi èso rẹ̀ ṣe wáìnì) níwájú mi,

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:7-12