Jẹ́nẹ́sísì 40:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Jósẹ́fù dé ọ̀dọ̀ wọn ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, ó ṣe àkíyèsí pé, inú wọn kò dùn.

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:4-11