Jẹ́nẹ́sísì 40:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fi wọ́n sí ìhámọ́ ní ilé olórí ẹ̀sọ́, ní inú ẹ̀wọ̀n ibi tí Jósẹ́fù pẹ̀lú wà.

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:1-9