Jẹ́nẹ́sísì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Káínì wí fún Ábélì arákùnrin rẹ̀ pé, “Jẹ́ kí a lọ sí oko.” Ó sì ṣe, bí wọ́n ti wà ní oko; Káínì da ojú ìjà kọ Ábélì arákùnrin rẹ̀, ó sì pa á.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:1-9