Jẹ́nẹ́sísì 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣùgbọ́n Olúwa kò fi ojú rere wo Káínì àti ẹbọ rẹ̀. Nítorí náà inú bí Káínì gidigidi, ojú rẹ̀ sì fàro.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:1-13