Jẹ́nẹ́sísì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lónìí, ìwọ lé mi kúrò lórí ilẹ̀, mó sì di ẹni tí ó fara pamọ́ kúrò ní ojú rẹ, èmi yóò sì di ìsáǹsá àti alárìnkiri ní ayé, ẹnikẹ́ni tí ó bá rí mi, yóò sì pa mí.”

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:13-24