Jẹ́nẹ́sísì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìwọ bá ṣiṣẹ́ lórí ilẹ̀, ilẹ̀ kì yóò so èṣo rẹ̀ fún ọ mọ́. Ìwọ yóò sì jẹ́ ìsáǹsá àti alárìnkiri ni orí ilẹ̀ ayé.”

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:11-19