Jẹ́nẹ́sísì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa wí pé, “Kín ni ohun tí ìwọ ṣe yìí? Gbọ́! Ẹ̀jẹ̀ arákùnrin rẹ ń kígbe pè mí láti ilẹ̀ wá.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:7-13