Jẹ́nẹ́sísì 39:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́dà náà kò sì mikàn nípa gbogbo ohun tí ó fi sí abẹ́ àkóso Jósẹ́fù, nítorí pé Olúwa wà pẹ̀lú Jósẹ́fù, ó sì ń jẹ́ kí ó ṣe àṣeyọrí nínú ohun gbogbo tí ó dáwọ́ lé.

Jẹ́nẹ́sísì 39

Jẹ́nẹ́sísì 39:17-23