Jẹ́nẹ́sísì 39:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì wà pẹ̀lú Jósẹ́fù, ó sì bùkún-un, ó sì ń gbé ní ilé ọ̀gá rẹ̀ ará Éjíbítì.

Jẹ́nẹ́sísì 39

Jẹ́nẹ́sísì 39:1-7