Jẹ́nẹ́sísì 39:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó rò fún un pé, “Ẹrú ará a Ébérù tí o rà wálé láti fi wá ṣẹlẹ́yà wá láti bá mi lò pọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 39

Jẹ́nẹ́sísì 39:11-23