Jẹ́nẹ́sísì 39:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó pe àwọn ìránṣẹ́ ilé náà, ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ wò ó, ọkọ ọ̀ mi mú Ébérù kan wọlé tọ̀ wá láti fi wá ṣe ẹlẹ́yà. Ó wọlé tọ̀ mí wá, láti bá mi lò pọ̀, ṣùgbọ́n mo kígbe.

Jẹ́nẹ́sísì 39

Jẹ́nẹ́sísì 39:5-22