Jẹ́nẹ́sísì 38:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni èkejì tí a ti so okùn olódòdó mọ́ lọ́rùn ọwọ́ jáde, wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ni Ṣérà.

Jẹ́nẹ́sísì 38

Jẹ́nẹ́sísì 38:22-30