Jẹ́nẹ́sísì 38:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó béèrè lọ́wọ́ àwọn ènìyàn àdúgbò náà pé, “Níbo ni aṣẹ́wó (aṣẹ́wó ibi ojúbọ òrìṣa) tí ó wà ní etí ọ̀nà Énáímù wà?”Wọ́n sì dá a lóhùn pé, “Kò sí aṣẹ́wó kankan níbí”

Jẹ́nẹ́sísì 38

Jẹ́nẹ́sísì 38:19-25