Jẹ́nẹ́sísì 37:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù lá àlá kan, nígbà tí ó sì sọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀, wọ́n túbọ̀ kórira rẹ̀ sí i.

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:1-7