Jẹ́nẹ́sísì 37:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dá a mọ̀, ó wí pé, “Áà! aṣọ ọmọ mi ni, ẹranko búburú ti pa á jẹ, láìṣe àníàní, ó ti fa Jósẹ́fù ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ.”

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:32-36