Jẹ́nẹ́sísì 37:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó padà lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin rẹ̀, ó sì wí pé, “Ọmọdé-kùnrin náà kò sí níbẹ̀ mọ́! Níbo ni ẹ fẹ́ kí n wọ̀ báyìí?”

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:27-36