Jẹ́nẹ́sísì 37:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n mú un, wọ́n sì jù ú sínú kòtò. Kòtò náà sì ṣófo, kò sí omi nínú un rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:20-30