Jẹ́nẹ́sísì 36:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Óhólíbámà pẹ̀lú sì bí Jéúsì, Jálámù, àti Kórà. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ tí Ísọ̀ bí ní Kénánì.

Jẹ́nẹ́sísì 36

Jẹ́nẹ́sísì 36:1-12