Jẹ́nẹ́sísì 36:40-43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

40. Àwọn wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ìjòyè tí ó ti ọ̀dọ̀ Ísọ̀ jáde wá, ní orúkọ ìdílé wọn, bí ìpínlẹ̀ wọn ti rí:Tínínà, Álífánì, Jététì.

41. Ohólíbámà, Élà, Pínónì,

42. Kénásì, Témáínì Míbísárì,

43. Mágídíélì, àti Írámù. Àwọn wọ̀nyí ni olóyè Édómù, gẹ́gẹ́ bí wọn ti tẹ̀dó sí ilẹ̀ tí wọ́n gbà.Èyí ni Ísọ̀ baba àwọn ará Édómù.

Jẹ́nẹ́sísì 36