Jẹ́nẹ́sísì 36:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Ṣéírì ara Hórì tí ó ń gbé ní ilẹ̀ náà:Lótanì, Ṣóbálì, Ṣíbéónì, Ánà

Jẹ́nẹ́sísì 36

Jẹ́nẹ́sísì 36:11-26