Jẹ́nẹ́sísì 35:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù sì mọ òpó (ọ̀wọ̀n) kan sí ibojì rẹ̀, òpó náà sì tọ́ka sí ojú ibojì Rákélì títí di òní.

Jẹ́nẹ́sísì 35

Jẹ́nẹ́sísì 35:18-27