Jẹ́nẹ́sísì 34:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn rẹ sì fà sí Dínà ọmọ Jákọ́bù gan-an, ó sì fẹ́ràn rẹ̀ ó sì bá ọmọbìnrin náà sọ̀rọ̀-ìfẹ́.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:1-6