Jẹ́nẹ́sísì 34:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe bí àwọn ẹran wọn àti ẹrú wọn àti àwọn ohun ọ̀sìn wọn ni yóò di tiwa bí a bá lè gbà bẹ́ẹ̀, wọn yóò sì máa gbé ni àárin wa.”

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:18-25