Jẹ́nẹ́sísì 34:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa yóò fara mọ́ ọn bí ẹ̀yin yóò bá gbà láti dàbí i tiwa, wí pé ẹ̀yin pẹ̀lú yóò kọ gbogbo ọkùnrin yín ní ilà.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:7-22