Jẹ́nẹ́sísì 34:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kan, Dínà ọmọbìnrin tí Líà bí fún Jákọ́bù jáde lọ bẹ àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ náà wò.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:1-2