Jẹ́nẹ́sísì 33:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísọ̀ wí pé, “Jẹ́ kí n fi díẹ̀ sílẹ̀ fún ọ nínú àwọn ọkùnrin mi nígbà náà.”Jákọ́bù wí pé, “Èéṣe, àní kí n sáà rí ojú rere olúwa mi?”

Jẹ́nẹ́sísì 33

Jẹ́nẹ́sísì 33:7-20