Jẹ́nẹ́sísì 32:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ní màlúù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àgùntàn àti ewúrẹ́. Mo tún ni àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin. Mo ń ránṣẹ́ yìí sí olúwa mi kí èmi le è rí ojúrere rẹ.’ ”

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:1-9