Jẹ́nẹ́sísì 32:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọgbọ̀n (30) abo ràkunmí pẹ̀lú ọmọ wọn, ogójì (40) abo màlúù àti akọ màlúù mẹ́wàá (10), ogún (20) abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ àti akọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ mẹ́wàá (10).

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:6-24