Jẹ́nẹ́sísì 31:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

yóò jẹ́ ẹ̀rí wí pé èmi kò ni ré òpó àti òkítì yìí kọjá láti bá ọ jà àti pé ìwọ pẹ̀lú kì yóò kọjá òkítì tàbí òpó yìí láti ṣe mí ní ibi.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:42-55