Jẹ́nẹ́sísì 31:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá fìyà jẹ àwọn ọmọbìnrin mi, tàbí tí o fẹ́ aya mìíràn yàtọ̀ sí wọn, rántí pé, Ọlọ́run ń bẹ láàrin wa bí ẹlẹ́rìí bí ẹnikẹ́ni kò tilẹ̀ sí.”

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:45-54