Jẹ́nẹ́sísì 31:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lábánì sì wí pé, “Òkítì yìí jẹ́ ẹ̀rí láàrin èmi àti ìwọ ní òní.” Ìdí nìyí tí a fi pe orúkọ rẹ̀ ni Gálíídì.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:39-52