Jẹ́nẹ́sísì 31:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún àwọn ìbátan rẹ̀ pé, “Ẹ kó àwọn òkúta díẹ̀ jọ.” Wọ́n sì kó òkúta náà jọ bí òkítì wọ́n sì jẹun níbẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:45-55