Jẹ́nẹ́sísì 31:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ni Ọlọ́run Bẹ́tẹ́lì, níbi tí ìwọ ti ta òróró sí òpó (ọ̀wọ́n), ìwọ sì jẹ́ ẹ̀jẹ́ láti sìn mi. Nísinsin yìí, kúrò ní ilẹ̀ yìí kíákíá kí o sì padà sí ilẹ̀ ibi tí a gbé ti bí ọ.’ ”

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:7-21