Jẹ́nẹ́sísì 30:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bílíhà, ọmọ ọ̀dọ̀ Rákélì sì tún lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kéjì fún Jákọ́bù.

Jẹ́nẹ́sísì 30

Jẹ́nẹ́sísì 30:1-8