Jẹ́nẹ́sísì 30:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà kígbà tí àwọn ẹran tí ó lera bá ń gùn, Jákọ́bù yóò fi àwọn ọ̀pá wọ̀nyí lélẹ̀ níwájú wọn, ní ibi tí wọn ti ń mumi.

Jẹ́nẹ́sísì 30

Jẹ́nẹ́sísì 30:35-43