Jẹ́nẹ́sísì 30:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí àwọn ẹran sì ń gùn, níwájú àwọn ọ̀pá náà, wọn sì bí àwọn ẹran onílà àti alámì, àwọn tí ó ní tótòtó lára.

Jẹ́nẹ́sísì 30

Jẹ́nẹ́sísì 30:30-40