Jẹ́nẹ́sísì 30:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibi tí Lábánì àti Jákọ́bù sì wà sí ara wọn, sì tó ìrìn ọjọ́ mẹ́ta. Jákọ́bù sì ń tọ́jú agbo ẹran Lábánì tí ó kù.

Jẹ́nẹ́sísì 30

Jẹ́nẹ́sísì 30:29-40