Jẹ́nẹ́sísì 30:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kó àwọn ọmọ àti ìyàwó mi fún mi, àwọn ẹni tí mo ti torí wọn sìn ọ́. Ki èmi lè máa bá ọ̀na mi lọ. O sá à mọ bí mo ti ṣiṣẹ́ sìn ọ́ tó”

Jẹ́nẹ́sísì 30

Jẹ́nẹ́sísì 30:21-33