Jẹ́nẹ́sísì 30:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Ọlọ́run rántí Rákélì, Ọlọ́run sì gbọ́ tirẹ̀, ó sì sí i ní inú.

Jẹ́nẹ́sísì 30

Jẹ́nẹ́sísì 30:19-32