Jẹ́nẹ́sísì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò sì fi ọ̀tásí àárin ìwọ àti obìnrin náà,àti sí àárín irú ọmọ rẹ àti irú ọmọ obìnrin náà;òun yóò fọ́ orí rẹìwọ yóò sì bù ú jẹ ní gìgísẹ̀.”

Jẹ́nẹ́sísì 3

Jẹ́nẹ́sísì 3:10-24