Jẹ́nẹ́sísì 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin náà wí pé, “Obìnrin tí ìwọ fi fún mi, ni ó fún mi nínú èṣo igi náà, mo sì jẹ ẹ́.”

Jẹ́nẹ́sísì 3

Jẹ́nẹ́sísì 3:10-15