Jẹ́nẹ́sísì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ejò ṣáà ṣe alárékérekè ju àwọn ẹranko igbó yóòkù tí Olúwa Ọlọ́run dá lọ. Ó sọ fún obìnrin náà pé, “Ǹjẹ́ òtítọ́ há ni Ọlọ́run wí pé, ‘Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ jẹ èṣo èyíkéyìí lára àwọn igi tí ó wà nínú ọgbà’?”

Jẹ́nẹ́sísì 3

Jẹ́nẹ́sísì 3:1-2