Jẹ́nẹ́sísì 29:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù béèrè lọ́wọ́ àwọn darandaran náà pé, “Ẹ̀yin arákùnrin mi níbo ni ẹ̀yin ti wá?”Àwọn náà sì dáhùn pé, “Láti Áránì ni,”

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:1-13